Ibi ni mo joko to mo wora mi,
Mo ri ibi ti oju mi de,
Ti ese mi ti te ibe rara.
Ibi ni mo ti ri e larewa leniyan,
Mo ri bi oju re se gunrege to,
Ti ese re si rewa ni rin jojo.
Ibi ni mo ti soro si ilu ati iju
Ti mo ri okun ti o rusoke laalaa.
Ibi ni mo nwo aworan ila owo mi,
Ti temi o papo mo telomiran ra ra.
Ibi ni mo ti to pelu iwa re
Ti o jo ti awon eni isaju
Ti won gbe ni iwaju Ile wa.
Ibi ni mo joko ti ibinu ara mi rara,
Ti gbogbo ohun fi nlo bi afefe,
Igi nla soje bi egbere ti ndi eni kiri.
Ibi ni mo wa ti n mowon ara mi,
Inner peace and power of words designing in creative programmes
Wednesday, 24 February 2021
Bi mose mo
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment