Thursday, 9 June 2022

 

IWE OGUN 1

Ejinrin.ori ologbo ti sode, atare,ao kole lori jijo.


ORI okete gbegbe a o lo a fise eja aro ti la fun 're. A o iyere se lepe ni yo.


Ifun okete ewe ewuro a o fitele ape a o fibo pelu atare.


Ako alagba meta,ewe ewuro o fi Tele ko le ao fi ewe ewuro bo. A o fi atare le a o fi ewura no, jijo,lilo re, epo alma fila.

Ifun okete pelu ewe etiponola, etu ela, pelu imi ORUN, a o sa si iboji. A o mafin laro. Oko oloko ni okete ko.


Ose awure --egbo abifa ati ewe re, egungun olufa, egungun oka, ehaa okuku, ati ose dudu, lofinda ti a fe.ohun re-- Ibi oka ba si, ibi ere ba si lo onje won ba won,ibi lasso joko ni okuku too wa,


Ose awue---ewe titipoola,ewe omisimisi,adun,ose ati lofinda Olohun gidi,a o ko sinu awo amo. 


Comfort Ogundipe ao fi owo osi gba lemeeta, ao ma so wipe wegunwepe wegunwepe wegunwepe, we egun, we epe, we assasi, we abilu , to wa Lara mi danu, ao lo mo kahun bilala die pelu ose iwe ekan, ao gbele ao da iyo isebe sinu ile ti a gbe naa, ao fi ose na fo Ori wa sinu koto naa pelu adura.


Ewe osanketu (opa elesinrin)

Owulo fun afato ka gbo mimu, akele wu tegbotebo ka fi eyin adie kan tele kase kafi we a o je eyin yen, Asina awebi


Ewe awolu matee

Ogun awure ti odaju ni

Ao lo ja gure yi ni opolopo amo ako nipe ni gure nigbana ao pe ni awolumate ao gun ewe yi ni enu ona ti angba koja ao po lose eyikeyi ti oba wuwa ao fi oyi  po ose na dada ao ko si inu ike fun fun ijo ti aba fe kan kan we aje ijo alamisi ti oba di ijokeji tise ojo jimo ao ra ekuru fun fun laisi ata nibe ao se adura si ao fi wole ayika wa odaju 08107154122

Ewe gbomoyo





What are the health benefits of soaked alligator pepper and bitter kola in coconut water?


 


Soak alligator pepper and bitter kola in coconut water in between 2-5 days to treat these health problems:


1. Boosts ovulation


Alligator pepper + bitter kola soaked in coconut water helps boost ovulation in women and increases their chances of conception. Alligator pepper + bitter kola + coconut water is good for women trying to conceive.


 


2. Boosts fertility in women


Soaking alligator pepper and bitter kola in coconut water and drinking the combo after 2 days helps boost fertility in both men and women.


 


3. Treats erectile dysfunction


May also Interest You - Open on a "New Tab":

FIVE Health Benefits Of Coconut Water

Reasons you should add coconut water to your diet 

Garcinia Kola: The Magic of chewing just one Bitter Kola

Sugarcane Juice can help boost Fertility, Libido and…

Akwa Ibom pegs maximum Secondary School age at 12;…

How Ayamase has made Iru the most expensive in diaspora

Soak Bitter kola in coconut water For 2 days and experience improvement in your libido, erection, and cure to your premature ejaculation. Alligator pepper + bitter kola + coconut water helps a man to last longer in bed. It stimulates testosterone production. Take a daily cup to achieve this.



4. Regularises menstruation


Alligator pepper and bitter kola soaked in bitter kola helps restore ceased mensuration and regularises your menstrual flow. Women with scanty flow should take the combo drink of coconut water, alligator pepper and bitter kola. Take a cup of this combo morning and evening.


 


5. Treats constipation


Are you constipated, a cup of coconut water infused with bitter kola and alligator pepper will stimulate your bowel movement.




 


6. Enhances good sleep


A drink of alligator pepper + bitter kola and coconut water every night promotes sleep and treats insomnia.


 


7. Lowers blood pressure


Soak Bitter kola and alligator pepper in coconut water For 2 days and drink a cup daily for your hypertension. Alligator pepper + bitter kola + coconut water reduces blood pressure. But this is not a substitute to your BP drugs.


 


8. Lowers blood cholesterol


Excess cholesterol in the blood is not good for the body as it can cause cardiac arrest and stroke. Please take a mixture of alligator pepper, bitter kola and coconut water to help remove bad cholesterol from your blood.


 


9. Lowers blood sugar


The combo of alligator pepper, bitter kola and coconut water lowers blood sugar and diabetics can take it. Soak alligator pepper and bitter kola in coconut water for 5 days and drink the concoction daily. This should not be a substitute to your sugar drugs if you are diabetic.


 


10. Good for weight loss


Bitter kola + coconut water and alligator pepper promote weight loss by helping to burn excess calories.


 


11. Boosts sperm count


A man suffering from low sperm count (oligospermia) or azoospermia should take a daily dose of alligator pepper and bitter kola soaked in coconut water for about a month. The sperm count will increase.


 


12. Increases libido


Alligator pepper and bitter kola soaked in coconut water boosts libido in both male and females.


 


13. Shrinks fibroids


Drinking the water from Bitter kola and alligator pepper and coconut water daily is believed to help shrink and melt uterine fibroids but this is not scientifically backed.


 


14. Promotes lactation


Nursing mothers who take a mixture of bitter kola, alligator pepper and coconut water have developed improved lactation and breast milk production.




 


15. Treats breasts discharge


Is your breast bringing out water? Alligator pepper soaked in coconut water for one week is believed to help lower blood prolactin level and treat breast discharge…galactorrhoea. Please ladies who experience breast discharge when they are not breast feeding should see a medical doctor for evaluation….it may be something more sinister.


 


16. Burns belly fat


Ladies and men with big tummy takes a cup of alligator pepper, butter cola and coconut water first thing in the morning to burn


KASE RERE KARETI ATISUN. 


AKESU ALAJO 300,000  OLOJOJUMO:-


AKOKO NI PE ISE YI KONI ATUNBOTAN RARA KONI NI ETUTU TABI EJE KANKAN ASIRI BIBO NKAN NI.

MO FI ISE YI BURA BI ISE BAJE IRO KI OLORUN OBA SO IBUNU RE LEMI LORI KI GBOGBO OHUN TI MO NI PARE LOJU MI PATAPATA...ASE WA.

ISE NA RE:- ODIDI ORI ERE KAN, ORI OLONGBO DUDU KAN, INA ORI YUNYUN PUPO, EKU AFE KAN, IYE AGBE META, IYE ALUKO META, IYE ODIDERE META, OGA GBIGBE META, GBOGBO OWO TA NA PATAPATA LATI 10# DE 1000# EWE ALUPAIDA 201, EWE AJE 201, ATI ODIDI OLUBI OOJO AO JO GBOGBO OGUN YI NI DEDE AGO KAN ORU, AOTA ADI EYAN YIPO ARO YI TAN GBE OGUN NA KA, AO NI RO OGUN YI TITI YIO FI GBO TAN, BIO BA JOTAN AO PA ADIE FUNFUN SILE AO SO OGUN YI LE ORI EJE ADIE RE TITI YIO FI TUTU, AO WA RO OGUN NA SINU SERE, ASO WAJI LA FI GBA SERE NA LA RA AO DE LENU PA, AO RAN APO ASO FUNFUN AOGBE SINU RE, IBITI ABA GBE ISE YI SI EGBERUN KAN 1000# SINU RE FI DA LOKO WO.

OFORE:- AFEMI AFE, ASE OHUN AGBE LOSE IYE RE NI ARO, AFEMIAFE ASEOHUN ALUKO LOSE IYE RE NI OSUN, AFEMI AFE ASE OHUN ODIDERE LOSE IYE IDI RE BO EPO, AFEMIAFE, OJU OLOGBO NI SESE FI TAN INA , AFEMIAFE IBITI ERE BAWA NI ONUJE RE BA, AFEMIAFE ASE TI EJO NI FI FORI BALE FUN ERE , ORI AGBE NI GBERE PADE AGBE, ORI ALUKO NI GBERE PADE ALUKO, ORI ODIDERE NI GBERE PADE ODIDERE, ABA TI ALAGEMO BADA BI ORISA OKE GBA, NINU EGUN NINU SOSO NI MORIWO TISO.


TEMI TIYIN TO TO AGBADUN RARA JU BA YI LO...AFI OLE NI KAN NIO NI KONI SO RIRE.....O TUN E ERU MO SE....SE AMEN RE.....ISE YI DA PUPO FUN OMO LUABI KOSI APALARA ITELORUN SI TI TO GBE.


OBINRIN LE LO ABI OKUNRIN NA LE LO SUGBON NI TI OBINRIN TO BA SE NKAN OSU MA DE IDIRE, BENI BI OKUNRIN BA BA OBINRIN SU KO MA DE IDI RE......IBI TI MOFI _ SI OLUBI LOWA NIBE AKESU KI SE ISE BURUKU TI EEYAN BI ABI KU OGUN ANABO NI FA ABIKU....IBI ___ WA OLUBI NIO KI BASE AKO ABI ABO.


OGUN IBO

Owerejeje Agolo kan a o gun idaji mose, a o po iyokun mose, a o ma fi we Lee man lodun tabi emeji lodun.


OGUN IBO 2

Epa olomomeeta, a o ko omore kuro, a o fi eyin inaki igboro si, a o fi ori re de,a o fi own akese we, a o we ni dudu ati fun fun.

Tabi, ki yo okan ti arin kuro,a o fi irun ori monu we eyin inaki igboro sinu re, a ode a owe lowu akese,ati dudu pelu funfun, a ogba laws eta,a o pa akuko man fun.


No comments:

Post a Comment