Thursday 12 September 2024

AGBARA TAPA 1



 1.ATUDE
Isu ogirisako, eru alamo, ata-ijosi – 16, ao gunpapo mo ose, aof omi agbon kan po ose yi, aomaf epo pupa paara kia towe.

2.ASINA OWO
Ewe tude a egbo re, aolo aof ose iwe emeta po,ao lo un ojo meta, ao mawe ni ago mejila osanabo (12:30pm), kehinkehin meta un ojo meta.

3.  ASINA
Opolo nla gbigbe meta odidi atare meta, aojoopolo kan odidi atare kan, elekeji be, eleketa be,ao di si oototo ao maf miliki olope lo ni ibere osu(1st, 2nd, 3rd).

4.ASINA
Iwo agbo kan, ewe oriji – igbe adie, igbe ewure,igbe aguntan, aojowon papo, kosi atare nibe o, aoma fomi tabi Hot lo.

5.OGUN IKO
Epo ekika – igi teteregun – eru – aoko sinu ikokoaoma mu, ao da omi si, ao ma mu.1


 6.EYIN DIDUN TODAJU
Ikamodu meje – kuluso meje – eyo atare meje –etu ibon ojuda, aolo ni eyin odo, ao f sin gbere iyekiye si eyin, ao f sin gbere kookan si oju, ao feyitoku se onde mo idi.

7.ERO ATA SISONI
Imi pepeye – imi elede – ako okuta, ao lowon po,ao mafi pa oju ata na.

8.ORUN DIDUN
Ewe ito – egungun orun aja – odidi atare kan, aolo, ao fori po, ao mafi pa orun na, ni igbakugba.

9.ATEPA TODAJU
Egbo botuje – egbo ion – egbo arunpale – ewearojoku – eso orombo wewe mewa(10) – egboagbosa, ao ko won sinu ike tabi ikoko kan, ao fomi aro re, ao ma f we ese wa jade, iseyi daragidigan lamalo bi enikan ba lerisiwa pe ohun yioda ogun kale unwa.

10.OGUN MARAN FUN MAGUN TABI AISAN 
 Ewe ewon, elegun, ao gbo pelu omi, ao yoomire ao f se igbin nla kan je, kosi epo tabi yo.

11.APETA TABI APEPA
Isawuru kan – e ikun mejeji – omo inu ekuromeji – atare odidi kan, ao jo papo, ao lo, ao fsin gbere yipo egbegbe e mejeji.

12.AJEGBE TODAJUm
Egbo werepe – egbo ina unun – ese akukoadie mejeji – odid atare kan, ao jo papo, aodasinu adin eyan un lila.

13.AJEGUN
Egbo lapa unun – odidi aalagba merin (4), aoko meta sinuaope un jijo pelu odidi atare kan, ao ko ewealupaida lelori, ao jopo ao lo kuna, ao f osegbana po, ose yi papo, ao ko ose yi sinu igbaolomori, ao de igba yi, ao wa pa eje alangbakan toku le le ori omori igbayi a ori igbana,tare kan, ao jopo, aolo ao maf epo pupa la ni alale.

14.OSE ITUWO ALAGBARA
Aopa ako aowa gbe ose yi si origun yara un ojo meta,3
 odi ojo kerin kia to bere sini we, ago mewa simejila ni wiwe, pelu kehin-kehin tuntun. Peluogo olohun ide ara re yio tu.

15.AWURE OBINRIN
Ewe aaimonikonimora – ewe sawerepepe –irun iyamopo, ao gunpo mo ose dudu ao mafwe ni araro.

16.ATEPA
Eso laa pupa – oju ologbo lopolopo – omoatare lopolopo, ao gun won papo, ao fsingbere yipo ese wa mejeji, opo eyan lelo.

17.OGUN EYONU AWON IYA AGBA
Ewe ajeobale tutu – ewe aje tutu, aolowonpapo mo iyere, ao f se eran ewure jelepo niyo. Enikeni tobaje aseje yi odaju wipeeran ara re  di ewo un awon aje nu ni.

18.ISORA
Ori aparo gbigbe kan – odidi atare kan, ao jopapo, ao lo kuna, ao f sin igbere 21 si arin oriwa.ENIKAN ISE KAN.


19. ATEPA
A o ja eso lapa pupa meta pelu atare aka kan a o jo a o fi singbere yi orun ese mejeji.














No comments:

Post a Comment