Thursday 12 September 2024

OJISE

Ojise ina ni e ni, abi ti omi ti pa ina. ojise ategun abi ile. Se ojise emi ati okan ni ti e. Gbogbo yin le maye duro tori emi ni oludari gbogbo won. Imisi Ile, imisi omi, imisi ategun, imisi ina ko lejo are won, Won ni ipa ni gbe aye ni, toripe gbogbo won ni onje isemi aye, Gbogbo ohun ni ojise gbogbo ona yi la o to bi omi, bi ina, bi ategun, bi erupe, ko kokuro lorun eda aye. Ojise ina fi ina se alaye oro, be ni ojise omi na se ti e. Bi ina ba njo omi ni yo pa, ojise erupe ile najise ti e sugbon ina  inu ile njo bo oke ati ilu, ina samo tabi orun o je omi o mi to nfi nro lojo. Ojise emi ati okan ni jise ina, omi, ategun, ati omititi ile ti yo sele. Gbogbo ojise jeyin ti won pelu otitito, ojise emi nikan lara nimada. Ologbon, oloye, onimo, ati bebe lo ni ojise emi ati okan ti won ba ile je,aye ara won je, bi ogun, bi ija, bi idajo ina, iku kotan lowo won. Ojise emi wadi irorun de ibi ipalara. Bi awon ojise se jise iyo ni won jise ibanuje, ki ma wa ni gbogbo igba. Ojise emi e jise ayo ati alafia kari aye, e yeje ise ogun ati iku mo,



من أنا؟  ماذا أكلت؟  ما أمي؟  لماذا انا هنا؟  ماذا
 يمكنني أن أفعل  إلا الله.  وقدر الله أنه حي.  وقد تسببت العواصف في هطول أمطار لا حصر لها.  عدد لا يحصى من المنازل التي أصبحت منازل.  يتم امتصاص كميات لا حصر لها من الهواء.  لقد سقطت أشهر لا تحصى من الأمطار.  لقد مرت أيام وشهور وسنوات لا تعد ولا تحصى على البشر والأشياء.  في وقت ما سوف نعرفهم وفي أوقات أخرى سوف تختفي العلامة أيضًا.  إلا الرياضي الذي يبذل نفسه من أجل سعادته ومن أجل عائلته وبين أفراد أسرته.  إنها كلمة الحرب (الإرث) التي تسبب حرب السرقة.  عائلة الفرد هي أساس مصير الفرد.  ما هو الخطأ الذي يحدث؟  هل كانت مملوكة لي أم لا؟  إلا الله.  لا إله إلا الله، القوة والحكمة والعلم والهدى والعز والعز، والموت والخلود هي أشياء الله، وأشياء الحياة هي الأشياء التي جعل الله بها الحياة.  هؤلاء هم التاج والزيت ومصباح القدر.

No comments:

Post a Comment