Thursday 12 September 2024

ASIRI ILE YORUBA 1

 ASIRI ILE YORUBA 1


1.   IWULO EWE EFINRIN FUN ITOJU ILERA WA 


Iwulo ewe yi Po pupo sugbon opolopo wa komo iwulo e sugbon mofe Yonda ise kan ti ewe Yi wulo fun ni asiko yi nitori aisan yi ngba emi opolopo ti awon elomiran si n na million of naira Lori aisan yi 

Kini aisan na gan ? Aisan kindinrin eleyi ti awon oloyinbo npe ni (KIDNEY PROBLEM) BOYA KIDNEY STONE NI TABI NKAN MIRAN) 

Taba mu ewe efinrin yi eje ki aja kopo ni tutu oojo, eba mi San ni(wash) dada eba mi dasi Inu pot ti eba Fe lo e  gbe kana ka bu Omi si ni iwonba ti yio fi thick dada, eje ki afi sile sori Ina fun bi iseju mewa ko hoo dada Toba ti ho eje ki aso kale si egbe kan ko tutu dada Toba tutu ejeki aro sinu keg tabi Ike kan, 


Ale gbe si Inu ero amohuntutu( fridge or refrigerator)

Ki ama mu die die laro laro Toba tan atun le se omiran 


Owulo pupo fun kidney problem

Owulo fun eni ti pajapaja ba ndalamu

Owulo fun eni ti owo tabi ese re ba nku riri ni igba gbogbo

Owulo fun eni to hora bapo Lara e lati yo danu kuro Lara 

Eyin na lese lasan sinu Ile kegbe sinu fridge yin kema mu laro laro kose nkan nkan 


2.         ATÚDÈ_TÓDÁJÚ.


AO TU ÈFÓ GÚRE TÌDÍTÌDÍ, AO GUN EYO KÁFÚRÀ  PAPÒ MO, AO WÁ GÚN OSE DÚDÚ MO, AO MAFI OSE NAA WÈ LALALE, AO NÍWO BÀTÀ TIA BÁFÉ LOWE OSE NAA OO.


3.        ARIMOLE AWORO TODAJU


ISENA RE:-

Ogede omimi pipon mefa ao bo epo arare danu ao ko sinu ike kan o fi Owo fo papo Dada ao fo eyin adie ibile kan si ao fi po papo ao wa bu iyo die si ao fi po papo naa ao wa sese lore da sinu koto tia gbe sinu shop tabi abawole inu shop wa ao wa da igo epo pupa le lore ao wa fi bi afoku apadi bo Lori ao wa se adura si ao wa sese roo yerupe bo monle.


4.  GBOGBO ENIYAN TOBA MA NA OWO KAN TAN KOTO RI IMI KOLO DAN ISEYI WO OGUN KI OWO MA DA LOWO ENI  (NEVER GO BROKE AGAIN) 

Toba ku owo kan adan, adan afi ro igba igi.. Kosi bosele ri owo konitan lowo eyan tio balo ise yii, ati mari imi ki ikan to tan. 


ISENARE 

Ewe ako ibepe ao ja die ao gun papo mo ose toba wuwa ao ko sinu ike funfu kan, ao wafi kokoro (key) ilekun yara wa gun ori ose naa, ao mabu ose naa we ni emeta lose... 


5.     Iferan gbogbo  aye 

Isenaniyi...


Ewe owu akese tutu, ao gbo pelu Ori (Shea butter) Omi agbon la o Fi gbo, ao Ra Lofinda bintu-el-sudan iGO kan ao da sinu re ao ma Fi pa oju ati gbogbo Ara wa  pelu asetiti ólóhun aori anugba 

6.   BIBO ASIRI

Ewe eyonbisowo, ewe ola pelu Owo tuntun, ao ki idi eyinbiso bo Inu igo, am I correct sir

Small coaster Biscuit, iyerosun to mark ogundabede and pure insde the gin, #1000, ewe olube the head will go inside the bottle first,  we will kill White local egg for it.


7. OGUN IFERAN TODAJU TI OBINRIN YIO FI MA NIFE WA, TABI OKUNRIN MA FI NI FE WA DADA

ISENARE  

ALUBOSA NLA FUNFUN KAN

PAPER WHITE

IYO DIDI

ODO TI KI GBE( RIVER) 

ORUKO OLOLUFE MEJEJI, TI KO NI ORUKO IYA WON NINU, (NO MOTHER NAME REQUIRES)

OWU DUDU ATI FUNFUN 

ISE NARE 

Ao fi Iyo yen ko Oruko awon mejeji si ori paper funfun na ao wa we ni owu dudu ati funfun po ao tun ge alubosa yen si meji dede ao wa fi ise ise ti awe yii si arin mejeji ao tun wa we ni owu dudu ati funfun tibi kankan koni yo sita rara

LILO RE 

 A o wa lo ri si odo to nsan.


8.  ASIRI TI AFINRI OWO NLA LONAKONA TI KOSI NAWA NI WAHALA RARA TODAJU 

                  ISENARE

 

Eepo idaba eyin ibile to sese pamo gbogbo eepo eyin naa, #1000 tuntun kan, agbon toni omi ninu  


                  SISERE 

A o mu epo idaba eyin adiye to sese pamo, a o ko gbogbo epo eyin naa, sugbon oni asiri nla kan towa ninu kiko epo eyin yi oooo, a o gbodo fi owo wa ko epo eyin naa ooo, a o fi igi ati abo kan ko sinu odo wani ooo, a o fi blue  biro tuntun ko account number wa sinu owo naa ati Oruko wa ati ti iya wa sinu re, a o se opolopo adura si owo yi gegebi asefe owo si, a o wa lo owo yi loju olo, a o ko Sara epo eyin towa ninu odo a o wa gun papo daada, a o wa gun papo, a o ko lose funfun eyikeyi, a o fi omi agbon popapo daada, a o ko sinu ike funfun nla kan,a o gbe aje olokun nla kan le lori, a o depa, a o gbe pamo fun 7days, leyin ojo keje, a o mafi kehinkehin tuntun we ose naa lararo,iseyi daju gan nio mofi ojo ti yoku emi ati eledami ni sare burs fun yin, asiri Ise toma gbe owo nla wa fun yan nio

9.  OGUN KOLEMAJA MI

1, Omonile kan 

2, Epo Eyin atare kan


A o yo Gbogbo nkan to wa ninu atare kuro, a o wa ti Omonile kan bo ninu, a o wa fin owu dudu ati funfun ko dada, A o wa gbe ko Enu ona Ile wa tabi Ile ISE wa or Ile itaja wa. Ogun yi kere loju SUGBON hmmmm Ina ni.


10.  ASIRI AWON AGBA ATIJO NI NITORI LO KO DATE ONI SILE TORI ONI GBAGBE OJO ONI LAYE RE... SI DADA NI OO 


 AṢIRI yii dara pupo sungbon lo ko date Oni sile, tori Oni gangan lo Mon wipe asiri wa ati wipe Oni gangan lo Mon Boya aye lowa nidi ore re nii, abi eniyan ...sungbon wa gbo mi loni oo ,  asiri wa nibi to wa , mo wa post ise yi loni fun opolopo awon eniyan lati je afani re ,  


ISE NARE 


Lo wa eyin agric meta pere , Koni sise fun o ti o ba ti comment ki o de share re oti di ase tori fun afani awon elomi na, eyin agric meta pere ati Ike funfun , ao wa lo ja ewe iyalode die , ao wa gbo ewe yii ninu Ike funfun yen , ao si Fi ase se idoti re Danu , ao si ju ............ meta yen sinu Ike funfun yen ao si gbe kana ,Toba jina ao se adura si wipe ona Koni di mon ,  lati oni ki ona mi bere sini la si rere ki owo nla wa ma Miri ,


LILO RE 


 Ao si je eyin na patapata , ona ma si fun onitohun gidi gan nii .. Ike yen Koni jona laye asiri nla Nii ,


11.  ASIRI IFERAN GBOGBO AYE TO GBONA GIDI GAN 

Ise yii tun ma sise asiribibo lara tio je pe owo koni fi igba kankan won wa. Gbiyanju ise yii wo kio dupe lowo eledua...


ISENA RE 


Ewe rerinkomi

Oju eyele (9)

Ewe ola 

Ewe sawerepepe 

Obi ifin (3)


SISE RE 


Ao lo gbogbo re papo tio kunna dada, ao da sinu lofinda SIX FLOWER...


LILO RE 


Ao ma fi para wa tia bati we tan, ao gbodo nu omi ara wa tia ba we tan oo ki ise yii bale sise dada ni ara wa. Ise yii daju pupo gan ni sugbon eledumare daju julo, esi je kia ma se jeje nitoripe gbogbo eniyan ni o ma feran wa  omode ati agbalagba...


12.  ASIRI OSE TI AFI N PADE OBINRIN OLOWO  GIDI FE, TABI OKUNRIN OLOWO GIDI FE  TABI TAFIN PADE ALANU OLOWO LONAKANNA LARIN OJO META SI MEJE PERE 


(ISE NARE 


A olo wa

Egun ori aja 

Ori akuko adie 

Ewe jinwinnii Oojo topo die 

Egun Ori eran agbo ibile 

Egun Ori  eran obuko ibile 

Ose eyikeyi topo die 


SISE RE 


Ejeka gun gbogbo re papo mo ose eyikeyi topo die Aoko sinu ike white nla Kan olomori 


LILO RE 


 A oma Fi we larolaro kato jade 


13.  OGUN IFURA

A o eko elewe kan a o hoo, a o toju aye alakan kan a o fi eko sinu abo tofedie pelu alakan di ojo keji ti a o bomo. A o je eyi tokun ni be, 


14.    OGUN ENITI NJALE

A o wa akisa atakìtan,a ojo pelu atare odidi kan,a o sa gbere si oju eni na,ti ao ti fi aso boju to ko ni ri end to nada fun. Eye kokan ni gbere na.


15.   ASIRI ISORA TIWON KONIFI JI EYAN GBE ( KIDNAP) NIBIKIBI TODAJU 

Enikeni toba ni ise yi lara,won koni ji gbe rara, Ise tia ti danwo dada ni


ISENARE:

Ao wa eku asin tutu kan tope lara dada

odindi atare kan


SISERE: Ao kowon sinu ape ijogun kan,ao jopo,ao lo kuna dada,ao ro pamo


LILORE: Ao bu die nbe,ao fisin gbere meta meta si orikerike gbogbo ara wa, ale sin fun iyawo wa ati awon omo wa na Toba wuwa


Efo odu, ina ata ijosi,eha inu posi,ao gun po mose si inu Ile funfun, oro re-gbogbo eniyan ni owojo han efo odu, teru tomo ni owojo reta,bi a ba ru posi wolu odidi eni nigba. Owo nlanla ni ki won fi fun mi.


Aje ara tagiri, ogiri, ewe ologbodu,ao gun mose. Ao ma we.


Igi ayin to gbe ku si ori iya re,eyo atare mesan/meje,ewe ailu mesan/meje a o lo,gbere metameta lorike ara_a Darin.


Ewe agogo igun mesan/meje ati atare mesan/meje, a o je leyo kokan to a o gbemi.- gbogbonse

16.   EYIN DIDUN ATI ARARIRO

1. Ori, ewe ati egbo atoo, kafura,menthol. 


2. Ori ati ehan ori orogbun ti fi ro amala pee. 


1. Ewe abirikolo

Otin ogogoro, omi osan wewe(a o da mejeeji Papo ...,kahun Bilala die ati odindi atare kan. A o loo Papo.. A o daa sinu re... A o Maa dii senu ni EEMEJI LOJUMON... A o Maa fi yo enu naa. Owo enu.


How to stop the witches and wizards operation


If witches are disturbing you and u are having attacks, get 7 alligator pepper, wrap each one of them with dry scent leaf, put one each at 4 corners of your house and stone the remaining 3 on your roof, before sleeping in the night, you will catch the person..


May The good God expose all those coming through the back door to steal our blessings..


2. Oro alago

Owulo fun eyonu asina awon éléyé


Oro alago die edu igi inu aro tiwon ti dana dada dié ao wa gun mo eru alamo 9 fun okunrin 7 fun obinrin

Ao wa Po lose

Kosigba ti akolewe

Sugbon odara ki awe ose yieni aro kutukutu ki orun toyó tabi ale ni dede iwolesun

Odaju




17.      OGUN TI WON BA SAWA NI ADA KI O MA LE WOLE SI WA NI ARA


A o lo wa oju ologbo 21,Eso efo gbure ti ko lanu 21, Omo inu Atare 21, Ewe Ailu to ko ni iho rara 21, a o wa ko si Ori olo, A o wa lopo ti yio Kuna dada a o wa fi sin gbere kokan si orikerike ara wa Hmmmmmm Yoruba ronu


NOTICE: Eni kan ni ise yi wa fun ooo ati Enikini ti o ba fi ise yi jale tabi se ibaje Ogunlakaye lomapa eni na (Ase).


18.   SPERM BOOSTER


Ingredients


1. 2 🍌 banana

2. One piece of Garlic 

3. Half tin Liquid milk 

4. Handful of Groundnut

5. Pinch of Ginger

6  2 seeds of Clove seed


Procedure

Blend all together and drink  two times in a day, go for test after 2weeks.


Epo eyin adie ... Ao lo ti yo kun naa Dada.. ao wa fi singbere yipo idi waa.

.. o n sise fun (magun.).....


Eyonu ni ti Eba fi padi  atare kan pelu epo eyin Mon eojo po ti yoo kun na     e o ma fi oyin loo



OGUN IFERAN TODAJU 


Ao lora awon nkan won Yi 


Ori ofafa eyo Kan 

Aso ere ibeji

Ewe iyeye

Ewe akonimora

Odindin atare eyo Kan 


Aojo awon nkan won Yi  papo ao wa lopapo ao wate ni ifa ejiogbe  

Obe ni ao mafise fun eni tia bafe lofun Koda kio se wipe oga ile ise ni afelofun tio baje ninu obe yi yio nife wa di ojo ogbo ni 

Koda kio se wipe larin oko si aya ni tio bati je ninu obe nan yio nife wa di ojo ogbo ni koda larin okunrin si okunrin 


Ikilo tio wa nibe ni wipe akogbodo lofun eni ti kosi ifere ni okan wa oooo 


MAJELE ERAN

Egbo igi emi a o re lagbo tutu pelu suga ati iyo fun ojo meta, a o fi fin igbo fun eran bi maalu. Note kogbodo kan enu mo o o.


OGUN IFURA

A o eko elewe kan a o hoo, a o toju aye alakan kan a o fi eko sinu abo tofedie pelu alakan di ojo keji ti a o bomo. A o je eyi tokun ni be, 


OGUN ENITI NJALE

A o wa akisa atakìtan,a ojo pelu atare odidi kan,a o sa gbere si oju eni na,ti ao ti fi aso boju to ko ni ri end to nada fun. Eye kokan ni gbure na.


ASIRI ISORA TIWON KONIFI JI EYAN GBE ( KIDNAP) NIBIKIBI TODAJU 

Enikeni toba ni ise yi lara,won koni ji gbe rara, Ise tia ti danwo dada ni


ISENARE:

Ao wa eku asin tutu kan tope lara dada

odindi atare kan


SISERE: Ao kowon sinu ape ijogun kan,ao jopo,ao lo kuna dada,ao ro pamo


LILORE: Ao bu die nbe,ao fisin gbere meta meta si orikerike gbogbo ara wa, ale sin fun iyawo wa ati awon omo wa na Toba wuwa


Hapetite


EWE IBEPE, EGBO IGI IROKO, KUKU OLOKUN, AFARA OYIN, EFUN ILE


ASINA AGBALUMO

ISENA RE:-

AO WA KORO AGBALUMO TI ARIN PADE TI AKO MO ENI TOMU EYOKAN PERE..  TI ABATIRI AO WA PA PEPEPE LORI OLO, AO YO FUNFUN INU RE YAN AO LO MO OSE IWE EKAN PERE...


LILO RE:- 

TI ABATI GUN TAN LESEKESE LA MA LOWE...AO WA MA PE OHUN RE SI..


OFORE:- INU IGBO NI AGBALUMO NWA TI OMO ARAYE LANA LOBA.. KI OLORE EMI LAGBAJA OMO LAGBAJA WA MI KAN LONI LONAKONA.. NI KIAKIA..


Koropo ni wan mo fise ogun ibon 1

A o gbo pelu hot ni ao wa fi re singlet kan , lojo taba yo lere , ao lo w la ako alangba 9 atare aja 9  ao la awon alagba Yi laya ao ko ifun inu re sinu ape ijogun ao wa yo omo kan soso ninu atare aja nah ao di oju wa le Sonu Tani mo ibi to ba bo si , bi ao se jo leyo Koo ko kan nu ao wa Tani ikobere ao ta marun mo iwaju aso Yi 4 ni eyin re ,  mofi ifa bura asiri awon agba ni  eje kafi asoyi ko kayin ibon si koni lu wole

ASO OGUN 2

Ori agutan tutu,ori oka tutu, awo ijimere, obi abata oloju meta, obe ti won ko ti otidogun, a o jo ninu AGADA, ebu ni yan, a o wa bara egusi kan a o re pelu awotele tuntun,fun ojo meje, a o yo a o fi ebu na yi Aso yi a o sa siboji. A o di obe tokun ni ikobere si aso yi, tabi si ara.


ATUDE

Ewe awede, atare 16,ata ijosin 16,epo isele, igbin NLA kan ge si 16,Niyo aseje lale katosun. 


AKESU ALAJO 100,000  OLOJOJUMO:-


AKOKO NI PE ISE YI KONI ATUNBOTAN RARA KONI NI ETUTU TABI EJE KANKAN ASIRI BIBO NKAN NI.

MO FI ISE YI BURA BI ISE BAJE IRO KI OLORUN OBA SO IBUNU RE LEMI LORI KI GBOGBO OHUN TI MO NI PARE LOJU MI PATAPATA...ASE WA.

ISE NA RE:- ODIDI ORI ERE KAN, ORI OLONGBO DUDU KAN, INA ORI YUNYUN PUPO, EKU AFE KAN, IYE AGBE META, IYE ALUKO META, IYE ODIDERE META, OGA GBIGBE META, GBOGBO OWO TA NA PATAPATA LATI 10# DE 1000# EWE ALUPAIDA 201, EWE AJE 201, ATI ODIDI OLUBI OOJO AO JO GBOGBO OGUN YI NI DEDE AGO KAN ORU, AOTA ADI EYAN YIPO ARO YI TAN GBE OGUN NA KA, AO NI RO OGUN YI TITI YIO FI GBO TAN, BIO BA JOTAN AO PA ADIE FUNFUN SILE AO SO OGUN YI LE ORI EJE ADIE RE TITI YIO FI TUTU, AO WA PO ETU NA MON OSE DUDU AO WA IGBA ONI KOKO AO KO OSE NASI, ASO PUPA LA FI TE IGBA NAA NI IDI , IBITI ABA GBE ISE YI SI EGBERUN KAN 1000# SINU RE FI DA LOKO WO.

OFORE:- AFEMI AFE, ASE OHUN AGBE LOSE IYE RE NI ARO, AFEMIAFE ASEOHUN ALUKO LOSE IYE RE NI OSUN, AFEMI AFE ASE OHUN ODIDERE LOSE IYE IDI RE BO EPO, AFEMIAFE, OJU OLOGBO NI SESE FI TAN INA , AFEMIAFE IBITI ERE BAWA NI ONUJE RE BA, AFEMIAFE ASE TI EJO NI FI FORI BALE FUN ERE , ORI AGBE NI GBERE PADE AGBE, ORI ALUKO NI GBERE PADE ALUKO, ORI ODIDERE NI GBERE PADE ODIDERE, ABA TI ALAGEMO BADA BI ORISA OKE GBA, NINU EGUN NINU SOSO NI MORIWO TISO.


OBINRIN LE LO ABI OKUNRIN NA LE LO SUGBON NI TI OBINRIN TO BA SE NKAN OSU MA DE IDIRE, BENI BI OKUNRIN BA BA OBINRIN SU KO MA DE IDI RE......IBI TI MOFI _ SI OLUBI LOWA NIBE AKESU KI SE ISE BURUKU TI EEYAN BI ABI KU OGUN ANABO NI FA ABIKU....IBI ___ WA OLUBI NIO KI BASE AKO ABI ABO.


ISE DADA NI ISEYI KO NI ATUNBOTAN RARA KODA KOSI OJU TIO LE RI ISE YI SUGBON AGBODO PA GBOGBO EWO RE MO PATAPATA.



DEPENU

ogede omini dudu, sawerepepe tutu,jijo, fine eko tutu,pelu oro pe "ogede dudu koya busan omo buruku----sawerepepe pepe sori elepe".


ANU

Itanna sawerepepe topo die,lilo gbigbe re pelu iyo fun anu ati ore tita. Anu


ISORI

Ewe mafowokanomomi,epo obo, igbin topinu,ose, Ito igbin o rangi. Isori


AWURE

Ewe odan ti a be fun ewure, agbado ti awon ewure je ku, a o gun mose, sinu awo ebo, pelu oro re. ewure oni foju kan ewe odan komaje, ewure oni foju kan agbado komaje. Awure


AWURE

Epo eyin adie topa, owo eyo kudi, o a lo kuna,a o da sinu oti sinabu mimu laro laro. Awure


Sugbon mase alaimore tio bafe kosise fun oo. mase ko iseyi sile tabi se ise yi lai share re tori anfani elomiran kosi comment dupe lowo olorun ooo tio bafe kosise fun oo..

OPA IKU

Igi ira ati oruka kusanrin kan ti a o fi ti pa kan mo igi na. 





TÍ OJÚ ÀRÀ OBÌNRIN BÁ KÉRÉ, TÀBÍ KÒ TÈTÈ LÀ, TÍ OYÚN RẸ SÍ TÍ PÉ OṢÙ MẸSÀN


Èso Ọpẹlẹ Mẹtá 3, tíó lanu, ao jò pẹlú Odindi Atare kan 1, ao lọ kúnná dàda ao pò papọ mọ ose dudu, ALÁBOYÚN ná yíò má fí fọ Abẹ rẹ, wẹrẹ là má gbọ Làṣe Èdùmàrè


Kojoloti, mafowokanomomi ,ose dudu,shinapp or 7up.ita


EPO egusi,didi atare,ewe Oriji a o da mo mole,jijo, ego inu


Olorungo,shinapp gbo a o to pamo. Masumabi.

 

ATUDE TI KO NAWA NI 1KOBO 

ISE YI DAJU GIDIGAN 


Eje kalo wa eso lapa funfun kan to pon dada, Ao lo kuna dada ki a wa fi ose iwe ekan pere ko lori olo ao ko sori kainkan ibile , tio ba di ale patapata ti a koni jade sita mo eje kalo fi we pelu fifi epo pupa para latoke dele


IKILOPATAKI 

Eyinkule ni ao ti we ose yii nibi ti ao ti mawo sanmo 

Leyin na ao gbodo jade sita mo rara


Ohun ni won pe ni ewe koje koje  bi eyan bafe ni arun opolo ao jo pelu odindi atare aja kan ao da si inu ogi eni na a mu ogi yen otan


Ewe olosepetu,ewe Orombo, ose dudu, so fi ko eso oju ologbo,a o mafiwe. 


EPO eyin topa,owo eyo kudi, a o lo a toe logbe pelu gbolohun pe epo eyin ni bo asiri  eyin ogbe ko gbe ire Kimi. A o dasi inu seaman. Mimu


ABIWERE FUN ALABOYUN

Ayan tutu iyekiye ao gun kuna ao fi ose dudu po ose yi. Bi oyun na bati di osu mesan tikoni pe bimo mo niyio ma we. 

Koda ki omo debu ninu aboyun tele pelu ogo olohun yio pada si aiye toye. 


Ao mu odidi toletole eyokan pelu eyo atare mesan fun okurin meje fun obirin  ao wa je toletole pelu atare yi lenu,ao je titi afitan ni enu wa ni oooo,leyin iseju marun e test e,mofi olohun bura ada ko le wole.


Tole tole ni oruko re,won malo fun eni toba tole kopaje omode tabi agbalagba,ema jo pelu atare odidi kan,e malo kuna daada ewada sinu oti Lord efisile fun ojo meta ni eyin ojo keta ema mu ni gas kan ni aro ati ni ale ,mofi olorun bura lse ti o comfam ni


Ogun sukesuke ni ,e gun toletole loju olo ki okuna dada ewa Omi kekere sinu ikoko egbe kana edakini ti a gun yi si  ti obatutu ki eni na omu isuke kini se eni na mo.


Ewe orin,korojo itakun,lwulore ti aje banrin eniyan mole,okunrin ewe re mesan eyo atare mesan aodoju okuta tiafi logun bole aololeyin okuta na,eniti abafelogunyi fun yio durolori okuta gbere mesan,lori,laya ati eyin,  tobaje obinrin meje meje,aosisebe gege,aje funwa lase eledumare


AWURE TIWON FINBUN YAN NI EBUN GIDI BI OWO, ILE, MOTOR, PROMOTION NIBI ISE, AWON NKAN RERE ATO YAN WA LONAKONA. 


ISENA RE:-

Obi abata alawe meta 6,

Orogbo 6

Atare NLA 6

Aogunpo mo ose dudu aoko osena si oju igbin aofi Abere oporo 6 gun oseyi Lori aomafi we ni

ekan tabi emeji lose.


OFORE:-

Lodindi ni anmu igbin wale 3*

Odindi bayi ni Abere nran aso 3*

Odindi ni anfi orogbo tore 3*

Odindi ni anfi obi tore fun alejo 3*

Lodindi ni atare ndi tie wa saye 3*

Odindi owo Odindi ebun Niki omo araye owama gbe funmi.


 Otun sise fun iriran onje ao mu isin,eyitiolanu lori iyare aoni je kokanle aofi atare aja kan ha lenu aojo po ao sin gbere si isale oju wa pelu orun owo mejeji ati yipo orun wa.


ASIRI TI MAJELE KONI FI SISE LARA WA


Ao waa odindin agbon kan, ao gba omi inu re sinu cup kan ao wa da epo pupa si, ao po papo, ao gbemu... bi won baa fun eniyan ni ogun buruku je ni agbara olohun koni se ise kankan lara wa.. E je ki a ma mura tori awon ota bi ore..


Ewe obibee,egunmo oshe lasan kiefifo oriyin emawasowipe obibee bamibe orimi gbogbo aburu epe,asasi aransi aomase aduabe aomafifo odagan nio


ASIRI OGUN TAFI MU ENI TOJI NKANWA

Eyii ni ona abayo fun awon oloja nla ti won ko shop re tabi eni tiwon ko ile re ise todaju ni 


ISENARE:-

e lo wa esuru tutu ati adin, ao wa ge esuru

yen lori, ao da lu die ao da adin yen si inu iho

esuru ti a pa ni pansa ao wa pe gbolohun resi 8


OFORE

surusuru ni oro esuru eniti o ba jinkan bayi ki ara mani

titi yio fi dapada x3 ao wa di ni owu dudu ati

fufu ao lo ri mo orita meta.Lagbara olorun inira ni eni

yen ma fi da nkan togbe pada larin ojo

meta....odaju


ASINA  OWO ATI IRE

Ewe okikiri, ewe koropomu itakun la ma npe,a o gun mose, a ma Fi nfo Ori ti ona ba di, a ma fi iyerosun te ogbe alara,  Orin re:-  ewifun alara wipe morire, eso fun ajero wipe mo rire, ire to Sonu ire tide,okikiri ko Kiri kalu ko lo gba ire mi wa lowo okunrin ,lowo obinrin etc



M m


Omo ti Korin lasiko

Ewuro oju ona kan lilo pelu ose we see omo na.


Asthma


MORNING KABIYESI

LET HAVE THIS NATURAL REMEDY FOR ASTHMA

PEAK MILK

ORIGINAL HONEY

FRESH SNAIL LIQUID 

ALL OF THE SAME QUANTITY

STIR AND DEINK IMMEDIATELY 

IT COULD BE DONE ONCE OR 3 TIME CONSECUTIVELY


TO treat asthma,get mango seeds. Break it, remove the internal White seed cut into pieces,dry it to powder

Use with hot pap ( eko gbigbna)





This is money concoction work


Get one fanta drink

Get four agric egg

Get one local pot or any clean pot you have

Get anti wicth back ( epo obo)

 Grind the anti wicth back into powder

 Put the anti wicth back you grind inside pot. put four agric egg on top it are pour  half fanta inside it are cook it after he done put it on top white cloth like you seen in the picture pray your wish prayer on it are eat it after you eat it  drink the remaining half fanta too flush it down.


ALEKO MOKOGUN BE NILE BAYI FUN TITA AGUNMU DARA GIDI FUN RE BANIFE SI KO KAN SI LORI WHATSAPP NUMBER MI 


AGUNMU ALEKO KICK AND START TO GBONA JANJAN----ise agunmu yi buru to bee gee,oju ese ti aba ti lo agunmu yi ni nkan omokunrin wa yo ti gbera,ti yo si le Koko bi irin,amoran mi ni wipe,ti a ko ba ti setan lati ni ibalopo,a ko gbodo lo, agunmu to le Koko ni,a o wa egbo ogbolo to gun to apa,a o ge ke ke ke,a o sa ti yo gbe,a o wa ogede agbagba dudu bi meta,a o ge ke ke ke tepo tepo,a o sa ti yo gbe daadaa,opolopo ewe guava, ododo asunwon to po die,iyere,egbo akogun, egbo igi gbogbo nse,a o je ki awon eroja yi gbe daadaa,a o ko sinu odo,a o gun kunna daadaa,a o mo fi mu eko gbigbona nigbati a ba ti nise nikan, nigbati o ba gba iyawo re my,oun na yo mo wipe aye ku sibikan,o tun ma je ki eeyan ko pe Lori obinrin,iwo danwo Loni,ko yin olohun oba Allah logo, danwo ko wa dupe.


ASIRI ISE IFERAN APE PADA IFERAN LAARIN OKO ATI AYA TODAJU TESTED AND CONFIRM ✅ 


GBOGBO EYIN TI IJA WA LARIN YIN ATI OLOLUFE YIN TIE SI FE KOPARI, ELO DAN ISEYII WO.. ABI EYIN TI OLOLUFE YIN KOSE DADA SI YIN MO. SARE LODAN ISEYI WO.. ODAJU GIDI... 


ISE NARE 


Ao wa candle funfun meji, ao fi abere (needle) ko oruko okunrin sara candle kan, ao tun fi abere ko oruko obinrin na sara candle keji, ao wafi omi lasan pa awan candle mejeji lara lati oke dele, ao wa fi photo eniti afe se si ranp ara ibiti ako oruko tiwa si, aowa fi photo tiwa na ranp ara ti ekeji ti ako oruko Ololufe wa si. ao wafi owu dudu ati funfun we candle mejeji papo lati oke dele, ao wa ope oyinbo kan (pineapple) ao pani pansa lori, ao wa gbe candle na sinu re, ao wafi omori tia ge lori re de pada, ao tun fi owu dudu ati funfun we bakanna, ao wa lori ma bebe odo (egbe odo) tonsan dada tojasipe omi yio ma gbe oke re koja nibi tia ri ise yi ma walahi confirm ni ise yi, ti ise yi ba se ntutu beeni okan obinrin na yio se ma tutu siwa odaju gan iwo ti obafe se ise yi tabi ti o fe ko kale dakun jeki nri owo re labe comment nitori ise yi ki nse ise toye ki nfi kale sori afefe. Ise nla...


ASIRI IFUNPA TI AFI NSO AWON OTA WA DA DINDINRIN LOJU IJA TI OJU OGUN BALE TOJE TESTED AND CONFIRM NI ✅


MOKI GBOGBO EYIN EYAN MI NINU ILE O



ENI TI ASIRI YI BATI WA LARA RE , GBOGBO AWON TOBA FE KOJU IJA SIWA LA MA SO DA DINDINRIN.


ISE NA RE 


AO LO WA IPE OORE MEJE, ORI IKUN NLA KAN,  AKISA ORI AATAN, ODINDI ATARE KAN.


AO JU AKISA NA SINU ABO KAN, AO BU OMI SI, AO KO EROJA TOKUN SINU IKOKO, AO JO, TOBA KU DIE KO JO TAN, AO YO AKISA NA NINU OMI, AO JU SINU NKAN TI ANJO YI, AO JO PAPO, TA BA JO TAN, AO DI SINU ASO FUNFUN TO NIPON PELU OWU DD ATI FF, AO WA FI SINU ODI AWO FUNFUN, AO RAN NI IFUNPA, , AO MA DI SI APA ALAFIA, ASIRI YI NSISE RESPECT, AMO, TI AWON ENI IBI BAFE SURU BOWA LATI BAWA JA TABI SE WA NI IBI, AO NA APA TI ISE YI WA SOKE PELU GBOLOHUN YI, , LOJU ESE NI GBOGBO WON YIO DI DINDINRI SORI IDURO, TI AWA YIO SI BA TIWA LO.


GBOLOHUN RE 


IKUN LONI KI APA OKUN YI, OORE LONI KO RE YIN WESI. BI AKISA BA BOSINU OMIN, WESI NI N RE.


OGUN OHUNMO TI ANFIN DA ALEJO LOUN

ilé agban

Ori ako ekute 🐀 ile

Imo ọpẹ

Awo lihili

Iye akala 3

Odindi atare 1

Aojopo aolokunna dada aomafi Odindi eko kan ló iwanba tí ababu nibe, bí a otise Malo nìyẹn,

OFORE.... agbelemo niti agban, agbelemo niti imo ope, bí ekute ile bagún oke aja, ari òun ti baálé ilé fi pamo sínú ilé, gbogbo ara ní lihili finrina, bí òkú Baku láyé, akala agbe orun ma aniyan,


ABAMODA #50,000 OJOJUMO TODAJU.


          Eroja....

EWE ABAMODA oni gaga meta

Owo pepa to tobijulo ni ilu tawaa eyokan...pere

Eyin eyele eyokan, eyin aparo eyokan.

Eyin alapandeedee eyokan

Aojopapoo... Aorosinu ado ijamo, aogbe adoyi sinu apoti funfun..ojumiran kogbudori...

Bi ogo se nje tolorun obami edumare.. Ti abaloye iseyiwo ni ojo keji aoti baa 500000 ninu apoti yi...sugbon aogbodo timu owoyioo.. Aoje koto ojoketaa kato bere sinimu owoyioo

Tor kojubeeloo


NOTE: iseyi kole loju osumefaa loo tofima denu kolee, beeni ani anfani lati tunse.

 Jowo fi emo imore han ni abee post miyi..tori akokoteminani mofikale lati kò atejiseyi..

Fun Iwo tikobale  Raye sise iseyi..boyaa fun idikan tabi idikeji kansimi maa baa oo se.

Ti ohunkohun baru o loju ninu iseyi beree madaa olohun..

Jowo mako iseyi kale lasan  bamidanwo


EYI NI OSOLE OWO 600 thousands LAARIN WAAKATI MEERIN KIAKIA TODAJU


OWO EYO 16

AKO ALANGBA KAN

ABO ALANGBA KAN


SISERE: AO KO OWO EYO MESAN SI ENU AKO ALANGBA AO KO MEJE SENU ABO ALANGBA AO JO WON PELU ATARE KAN SOSO,  


AO FI MILK AGOLO KAN LO LAI FOHUN SEYAN LARO..


OSHOLE OMO YAHOO 

Iseyi dapupo fun omo yahoo yiojeki oni client tolowo lowo tiyiosiri owo gba lowore 

ISENA NIYI 

Eye adankan ewe jeminiho topo ati ewe abamoda pelu odidi atare kan aojo papo aolo tiyiokuna aoda si onameji aofi idakan sin gbere yika orun owowa mejeji aoda ikeji sinu oyin amanla nigbati abafe ba client soro iseyi dapupo tosidamiloju fun enitioba lafojudi 


ASINA OWO AGBAOJO ASIRIBIBO

 TODAJU


Ewe Abamoda

Eyo Atare 21

Oti 33

Ao ja ewe Abamoda to wa ni arin eyo kan,Ao ko eyo Atare 21 si ni arin,Ao se aduaa owo si daada,ao jee ,ao mu Oti 33 le ni ori

Eledua yii oo gbo aduaa wa o


BIBOASIRI GRACE

A o wa ekuru funfun pelu grace perfume kan , akoni fii iyo sinu ekuru yen , awa gbadura sii inu e , leyin naa ,awa mix grace perfume sinu ekuru yen ,


LILO RE 


 A o wa Fon sile ni dede ago mejila oru .. emeji losu lo gbodo se , haaa ise yi kere nitoto sugbon o lagbara pupo gidi gan.. Wa ma ri owo nii onakona pelu irorun , odaju pupo. 



No comments:

Post a Comment