Thursday 12 September 2024

AKONI 1

Iwe Ogun Ibon Ati Ada Vol.1

by

woli adejorin 

 

IWE OGUN

IBON ATI ADA

Lat owo woli Adejorin Michael a k a iyamah iyamah Tel. +2348038891962 / +2348122840384

1, OGUN IBON TODAJU

.

Obi abata alawe mefa (6), odindi ataare kan, pata funfun kan,singileti funfun, handkerchief funfun kan.SISE RE:- Ao wo pata naa, pelu singileti, ao wa pin obi yen si onamefa, ao bo atare yen kuro ninu epo re, ao pin si ona mefa naa,ao to ni atare kan obi kan titi yio fi pe ona mefa ni enu ona wa. Aokun le tii ogun yii ao ka apawa mejeji seyin, ao bere sini fi enu gbe je. Ti aba ti jetan ao mu oti eebo le opari.

 

2, ASO ERE FUN IBON

Ewe agogo igun a o tu tegbotegbo idi mesan,ao ra ikoko tuntunao ko ewe ye idi marun tele ninu koko ye na ao ra singlet tuntunao fi le lori ao wa ko idi merin toku le lori ao bu omi si ao se tomaho daada ao yo aso ye kuro ao sa to ba gbe ao ma wo si isaleaso wa kosi ibon naa to ma wole si wa lara

3, KII IBON DI ODI KO MAALE SORO TI WON BAYIN

ewe iroko eyokan ao fi we orogbo kan ti ko gbodo han sita Ao jea ko gbodo ya enu ti ao fije tan.be enina ko gbodo soro si eniyanti yio fi je tan.

4, TI WON BA FE NAWA NI OGUN BURUKU TABI FIBONILOWO,OWO OLUWA RE YIO KAKO,OJO NA LO MAKU...

Ori oka nla kan,adigbonnaku lopolopo,ewa ikakure to Kako daadalopolopo,ao jo po ao lo kunna daada, gbere meta ni waju ori àtiipako,meta ni oke egbe eti osi àti otun.....Lobatan.....Odaju biiku,owo re yio Kako titi ti yio fi ku nio

5, ATIDIJO TO DAJU TI KO NAWA JU #50 LO

eo lo wa eyin ororo kan eo fi omi inu igi,abi ito aifohun se,ao mulosi ori akitan olojo pipe tia ba tife ya igbe,tigbe base njade ni idi wa ni esekese ni ao so eyin yi si enu ti eo sijetepotepo,Ko si nkan ti ko mu.ewore,ao gbodo je eyin abo mo,ao sigbodo do obo lateyin lobaten.

6, OGUN IBON TI IBON FULANI KOLE MU:

 Ado ijamo kan ao dalu Lori ao da omo inu re nu lai fe ategun sinuado yeoo ao wa ewe eyinolobe ao gbo po mo iyo dada ao wa kisinu ado ye tiyio Kun demudemu ao fi igi bomubomu diilenu pa aowe ni efewu ao di ni ikobere ao wa ran owo eyo ti ko luju meji molara ni egbe kookan ao lo palawo funfun oju owo eyo naa yio jadelegbe mejeji Hmmmmm eniba laya ko doju G3,MAk3,Ak tabi ibonFulani tabi bororo ko wallahi yio semi arare lofo nio

7, KI IBON MALE SORO

 Awo iki Ifun aja Danadana 9, Labalaba 9 ,Eyo atare 9,Ao gunwonpo,Ao su roborobo Ao fi igi tisinu ifun Aja,Ao gbe nsinu Apadiijogun Ao fo eyin Adiye Meji si,Ao wa gbe pamo fun Ojo 7,LehinOjo7,Ao sagbe Ao ran ni Aso funfun ao fi se igbadi Ti Abafedanwo Ao gbe ko Aja lorun.

8, AJESARA

 Ao toju igbin bonu kan ao pa ao fi Efon yin Ope ge si Ekiri mesanao lo wa ewe ailu mesan ti kolu Rara pelu ogoman Ope sonsoorire mokanla idi Ope kokan lao tige kokan ti yo fipe mokanla atieso afola mesan pelu iyere merindinlogun (16) Ao lo wan papo Ao

fise igbin ti age yen epo pupa koni ni iyo a ko gbodo fi irin tabi sibiiro obe na ni ori ina,ipele tio fi ge igbin yen lao fi ro obe najinna aogbe lo si ori odo tia man fi gun iyan jije orire ni ao ti Je ni agogokan oru ni ihoho Ao ni wo aso ikokan ni ao ma mun Ekiri igbin na ju si enu ako gbodo mun Meji papo titi ti Ao fi Je tan,(ibon,ada,aike,obe,gbogbo irin ogun Oti di ewo Lara wa niye o)

9, OGUN KI IBON DI OMI:

 Ao lo wa omi inu isa alakan ao fi gbo ewe rinrin ao ma mundiedie.NB:ti a ba fe yewo ao ro die sinu black nylon ao so ko ao wa yinibon si.Ibon naa yio di omi.Iba eyin ajuni loooo

10, OGUN IBON

eso ibepe kekere tio sese hun ao loja ao wada oju olo dele aoduro si ori olo na ni ihoho ao je eso na pelu atare aja odidi kan tiati bo epo ara re ti abaje tan ao wamu omi glass cup of water aowa so wipe moba iwo ise yi mule pe odi ojo ti eni ti oduro sori olotio si da omi simi lara ki ibon to ranmi

11, AYETA IBON TODAJU

ewe itoro, ao fi omi gbo dada,ao da sinu pot kan,ao da rice sinu pot naa,ao tun ko ewe itoro miran lee lori ti yio bo mole dada,aowa gbe kanna,ao se ti o ba jina,ao ko awon ewe orire ye danu,ao je rice naa o dajuooo TI_ABAFE_DANWOao da die lara rice ye sile fun adie kio je tio ba ti je rice yen, ao wayin ibon fun adie yen,walahi ise yii daju gan ooo gbogbo eyin tiesope kosi ogun ibon #_AK-47 tabi N-4 tabi pistol iwo dan ise yiiwo walahi ninu epe tabi adura wa fikan ranse ninu re

1

itanna sawerepepe 21,eyo atare 21,ao lopo,ao fi sin gbere yipoorun owo wa mejeji,ao nije ki gbere na ja papo ooo

12, AYETA IBON TO DAJU PAA

ewe ailu 201,tiko dalu rara,eyin ope towo sile funrare ko niye,odidiatare kan,ao ko gbogbo re sinu fila gobi tia tinlo dada,ao jopo,aoma fifo eko tutu mu lekokan , Nb:- eyin ope towo sile nigba ti wonkoiti ge igi yen sile nio

13, OGUN AYETA

ti ko Ni wahala ninu rara ko da ki won maa ro ojo ota ibon naa koni de odo wa laelae

1.
Eso bomubomu ao rora laa die ao wa fi eyin ororo kan sinure ao bu omi die si ao se ti yio jinna ao je eyin na epo re atieso yii ao jo po mo padi atare kan ao ko sinu owu otutu aodi ni ikobere ao gba ni awo dudu ao mafi si ara

2

ewe sewon lapa sewon lese ao lo kunna daada ao lo ewa funfun agolo kan Ni ekuru ao po Ogun yii mo lai Ni fi iyo si ,ao fi sinu ewe ao fi su ekuru yi si ona marun ti oba jinna enikan yio je eyo kan.koda ale yin ibon si ara ewe na a lati fi danwo ko ni ran rara.sugbonooo Abo olorun nipon ju gbogbo re lo o

14, OGUN IBON TO DAJU

Gege bi gbogbo wa se mo pe aye ti di aye BokoHaram bakan naa oro awon Fulani naa ko gbeyin won tipa omo olomo lekun kodaelomiran ti di alabo ara fun idi eleyii eje kia gba ogun ibon yi odaju bi ku Eje kia toju ibepe dudu kan tiko Kanle ao pani pansa ao wa fiafatan irun eni to fese ise yii sinu re pelu odidi atare kan ao jo po ao fisin gbere yipo ikun, Ikilo : - eni to ni irun nikan ni yio lo ise yiobi beeko hmmm

15, FUN AYETA IBON.

Orogbo odidi kan.Ao fi ewe oye we..Ao tun fi ewe iyalode we, Aoka ese kuro nile..Ao di oju wa,Ao so ipese yi si enu,Ao je lenu aosi gbe mi..Ao yaju leyin ti abaje tan,ao tun ka ese sile'(Odigba tiwon ba diju ti ese won ko si kanle ki ibon to le wole si eniyanlara.

16, OWO IBON YI DAJU KERE GAN GBIYANJU E WO

egun igi ata ao fi ada ha kuro lara igi re,egun igi araba ao fi adaha kuro lara igi re,ewu iyan ojo keji gbobgo nkan yi odi inu agbada ao jo bi aba jo tan ao lo yio kunna dada eleyi tia ba fe lo ao te ni ejiogbe,<OFO RE>egun ata kigun ata denu egun araba ki gun araba denu ewu iyan ojo keji kijo ni lowo ao fifo eko odidi kan mu odaju ju ada lo ogun.

17, OWO IBON,ADA,IGO ATI IGI

eso inu apawa meta(3)ao jo eyo kan mo odidi atare kan ao fifokomu lekana.ao jo eso ekeji pelu odidi atare kan ninu agbadamiran,ao fisin gbere yi ikun wa ka ebu ti o ba ku ao danu.ao joeleketa pelu odidi atare kan ninu agbada o to,ao di sinu owu otutuao di ni ikobere owu dudu ati funfun ao ran ni ifunpa,awoa ye ni ao fi bo oju ogun apa otun awo funfun apa osi awo duduodaju,mo juba eyin agba ajunilo eje ko ju mi se o.

18, OGUN AFANTA TO DAJU.

ao lo ra eso ose ao da ni pansa ao wo gbogbo omo inu re danuao fi koro owu ropo eso ye tomakun daada ao wa ki odidi atarekan bo inu re ao fi owo ki wonu re daadaa ao tun mu koro owumiran ao tun ki mo ao fi omori re de ao jo toba jo tan ao lo ti yiokunna ao ma fi eko elewe lo leekan kan odaju ti won banyin eyi keyi ibon siwa yio fundanu kole bawa odaju pa

19,OGUN IBON

 Ao wa igba olomori kekere kan ao fi ewe tagiri oojo tiko daluMesan tele inu re,ao bu rice iwonba ti aleje tan si,ao tun fi ewetagiri Mesan Miran bo ao bu omi si,ao de pa,ao gbe kana,ao se jina,toba jina tan idi re ko gbodo kanle,ao je,ti a baje tan a le dan

ibon wo lara eran tabi adiye ti a ba fun ni rice na je,ti eru banbawa,ki a de igba yen kia gbe sile ki adan ibon wo lara re

20, OGUN OKIGBE ATI IGO ATI IRIN

awo iki,werenjeje merindinlogun 16,omo irulamerindinlongun 16,omo atare merindinlogun 16 etu ibongidi nioo,ao gun gbogbo re po ti yio kunna daada ao wa fi singbere yika idodo wa ao tun fi sin yika inu wa lati idodo pada si idodo..

21, OGUN IBON TO DAJU.

ao lo o sa eyin to jabo fun raare 200,ao ko sinu agbada,ao fi odidi ataare nla kan si,ao de pa,ao wa dana si nidi,ao ni si wo toma fi  jotan,ao lo ao maa fi fokomu,laarin osu kan tabi meji si meta,koi  pegba loruko e, ti won ba yinbon siwa ao sope koipe igba,(henogoenter)untill ti won bayi igba ibon pe igba,ko de le pe,toripe ti a bati nso wipe koipegba,won a da wo duro,onka maatun pada seyin ni,ko le pegba afiti ao ba soro to fi pegba loku.

22, AYETA IBON TO DAJU

ori ako alangba,ao lo eyo atare mesan si enure ao wa jopo ao fi singbere mesan si aya wa odaju gan ni oo

23, OGUN AYETA AYIN KU..ATIDIJO TO DAJU PA.

ako alangba ati abo alangba ao ko eyin won sira ninu apeijo gun ao fi atare aaja kan bo laarin,ao jo papo.ao fi singbere lati iwaju ori de ibadi.n.b: - enikeni ti o ba doju ibon kowa ni yo ku o.

24, AYETA IBON

ti won ba fi aso pupa senu ibon koni ranwa. ao ge ori adaripon a ofi sinu ape ijogun wa,ao fi aso pupa die si,pelu odindi atare kan siao jo papo..lilo re : - ao fi sin gbere lati orokun ese de koko ese ni isalemejeji..odaju.

25, OGUN TI AFIN YO ATA:

ewe arojoku,odidi atare kan,ao jopo,ao lo etu ibon origina mo,aowa fi sin gbere dorika ibiti won ti sowa lata ao fi ebu yi ra

26, OGUN IBON ONIFILA

ao wa ako alangba aye ati owo eyo kan ti oluju ao tibo alangba yi lenu ti yio de inu re ao wa de male di ojo keji tio ba di ojo keji aowa po owo eyo ye jade lati idire ao waran owo eyo yi ma fila Gobi ninu ao ma de, yin ibon si fila yiwo tested and confirm aleloalangba ye fun nkan mi 

27, OGUN ATIDIJO IBON,TO SURE.

omo ayo tiwan tita dada 9,ao mi meseesan pelu eyikeyi(any),okele onje,ao wa ya mo igbe,ao fi akisa kan nu arawannudada,ao wa mu omo ayo 1,werenjeje 1,omo atare 1,ao fi sinu owututu ao di ni ikobere,ao sebe lona mesan,ao ko si inu abo kan,aowa pa eje

كاوبب

kan si,tia wan ogun yi ba ti fà eje re mu,ao ran gbogbo pata ni onde si ojukan na tabi kia ran mo ara bante,nb: - atidijo ni,,ti wan ba yin iban siwa,wallahi yio gba eyin jade nipelu ogo oloun.

28, OKIGBE

ikode kan,etu ibon oyinbo,egungun ori monu die,ao lo papo ao fisin gbere yika ori wa ni sale irun

29, AYETA IBON

ideri oti gudar meji,ao ko eyo atare mesan si,eso afola mesan siao de ao we lowu dudu ati funfun,ao ma fi sara jade

30, OKIGBE

opolo ijokun kan ao ko oruka si ninu ao lori mo ori akitan di ojoketa pere

31, AYETA

oju olongbo 16 ,eyo atare 16,ao di ni aso pupa ao ma fi sara jade

32, OGUN IBON ATI ADA

e lo wa odidi alangba adaripon kan eyin ororo tojoo nio tabi ti koba ti ju ojo marun lo,odidi atare kan e jo papo,gbere 14 si ori,14 siaya,,14 si eyin,ki e fi iyoku fokomu

33, OGUN IBON TIDIYO TO DAJU

Odidi eyin ibile kan,ao lu lori ao ko eyo atare 201 sinu re,ao lutagiri lori,ao gbe eyin ye sinu tagiri,ao gbe tagiri nah kana,ao selori adiro,ti obati jina,todipe tagiri tinjoo nidi,ao gbe tagiri kuro loriinaa,ao yo eyin na lati idi tagiri ao je eyin naa tepotepo laifi esekan le. Comfirm ni Joooo

34, IBON

ire sile ewe oparun 16 ,oju musu 16,eyo atare 16,lopogbere 16,si apa mejeji

35, OGUN TI WON BA FI ASO PUPA SI ENU IBON,
@

odidi orogbo kan,ao lo mi ao yo ninu igbe,ao dini asopupa,ao jo pelu odidi atare kan,ao fi sin gbere 9,si aya pelu eyin

36, IBON.

Eso ewe owu akese eyo meta,ewe rinrin ao jo po pelu odidi atarekan ao fi sin gbere si egbe otun ati tosi ni meta meta.

37, OGUN OWO FUN ONI FAYAWO TO DAJU

òkun Maka 1,Eko Odindi kan,Àkàrà elepo,Orun(neck)inúaaka,Odindi atare 1,Ao jo wan papo,ao ko sìinú aṣọ waji, ao dí pòniikobere ao ma fi sì àpò Sokoto ní igbàgbogbo.OFO RE..... Akiipé olórí kí ayo obe3×,Akiipe alákàrà kí ayo idà3×,Akiiri òkunMaka kía yín ibon3×,Orun tí aaka bale inú ara rẹ Lomanlesì...... Aniyan.Odaju ko da osise ju isuju miran lọ.A kiifi jalèooo,eni to bafijale to ba ja delọ òun ko ni yio pada wọlé lojona

38, AYETA

obi abata oloju meta3,ewe ogbe ori akuko eyo meta 3,eyo ataremeta 3,ota ibon eyo meta 3,ao la awe obi yen si ona meta 3,aomu obi abata awe kan 1,eyo atare kan 1, ewe ogbe ori akuko eyokan 1,ao lo papo ao fiota ibon kan 1 si ,ao su rugudu bi robo ao wa sa si iboji beni ao seshe meteta ao sa ao fi sinu okele ao su ao fi run obe ao gbe minojo meta ni ao filo ise yi odaju gan.e je ka she oto inu oto inu lo jaoooNote;

 

ao gbodo ya igbe si ori apata ooo ikilo ni yio ojo taba yaigbe si ori apapta gbogbo nkan taba min ni ao ya mon igbe ooo

39, OGUN OWO IBON TO DAJU

ao wa arigisegi ao ko oju olongbo mesan eyo atare mesan ao rosinu re ao we ni owu dudu ati funfun ao ma so moorun wa edanwo

40, "KOO WOLE IBON"

alakan kan,omole tope kan,odidi atare kan,ao jo ao fi fi sieyo kan si iwaju ori

41, IBON

oka baba pupa 21,oju werenjeje 21,eyo ataare 21,ao gunpo'gbere si ejika mejeji

42, AYETA TO DAJU

Ewe osan wewe,eso afola,eso oju ologbo,ao gun gbogbo re papomo ose.Ao waada eso oju ologbo sinu ose na.ao maa fi we.NB:-Bi eso oju ologbo na seun jabo,beeni ota ibon ti won ba yin siwayio ma jabo sile.

43, OGUN IBON TO DAJU

ibepe pipo kna ao ja ko gbodo kanle,ewe ailu 201oju olongbo201,eyo atare 201ao da ibepe ye ni pansa,ao ko awon nkanwonyi si ao fi ideri re de pada ao di lowu ko ma ba tu ao jo ao loao fi sin gbere 201,si ori wa odaju opo eniyan lo le lo.

44, OGUN IBON OLOSU METAMETA.

ewe etipon ola kan kogbodo luoo omo atare kan,ododo imi esukan ao ko won sinu ewe etipon ola yen,ao we papo ao ju sinu onaofun wa lo kogbodo kan eyin wa ooo,ao,ma,se,ni osumetameta,.....aje sara ibon niooooo

45, OGUN IBON

ao wa eso bomubomu tio tobi julo lori igire,ao ja,ao lo lori olo,aolora ogi tutu funfun,ao fi omi die fo ogun ti o wa lori olo si,ao popapo ao diju gbemi!!!!!!!!!

46, OGUN AYETA IBON TO DAJU

ao wa eso gure eyo kan ati eyo atare eyo kan ao gun papo ao fisin gbere meta si aya wa, e mase fi oju di ogun na nitori o daju

47, ASAKI IBON TO GBONA GIDI

ori omonile pelu ori ako alamu,ema ti ori omonile bo enu alamuewa fi sinu aso funfun e ran pa ele ran ni ikorun tabi ki ema fi
sapo lo ba tan ele sa sorun ki oba mama run mofi ifa bura lori iseyi bi won ba yin ibon lu yin ti ise yi de wa lara yi ibon na ko ni dunrara mo ibon na de ti baje niyen .

48, ASIRI TI IBON FULANI FI DOMI TABI ASAKI IBONTODAJUPECENT SURE GRANTED ,

eyin pepeye kan ewe eyinolobe odidi atatre kan sisere aof eyin pepeyesinu ape ogun wa aowa yin atate odidi kan lelori aowa da ewe yen bolori mole aojo ogun yen toba jotan aowa so ka ori table kan awa taeloogun yen ese wa kogbdo kanle rara, aowa duro sori odo tabaesingbere yen,aof singbere yipo ikun wa , eleyi toba ku ao f oekomu,dupe kole je un

49, ASAKI IBON TODAJU

ako alangba kan ao yin odindi atare sinu abo (plate) kan ao ko esowerenjeje sinu atare yi  yio po ao ma ko sinu alangba na  yio kundaada ao wa na oruka straight sinu alangba na  yio wole daada ao waf odindi atare kan ha lenu ao jo papo bio ba jotan ao ma f oruka nasowo ao ma f o lo ebu o ku na haaaaa ogun de kosi iru ibon won lekoju re siwa  yio dahun yio ma pacap ni koda ibi  ise yi je de  ba jeeni  o wa legbe wa ni won e yin ibon un ibon na koni dahunodamiloju biku

50, ASAKI IBON

efo rinrin tutu,ao fi tele ape,ao wa fi eyin adiye oronro kan, si ao fiomi ara efo yi se jina, ao wa je eyin yi tepotepo

51, AYETA TODAJU ..

itana ako ibepe oojo ao Jo pelu odidi atare kan,gbere meta meta lorikeara wa...ti aba fe danwo ao yin ibon fun IKOKO naa.








No comments:

Post a Comment